Tope Alabi – Oruko Jesu Mp3 Download (Audio) Free + Lyrics

On this page, you can download Oruko Jesu by Tope Alabi  in HD for free and read the lyrics.

Do you want a free download Oruko Jesu by Tope Alabi in mp3 (HD quality)? Afterwards, you can find the download link here on this page.

Track title: Oruko Jesu

Album: Igbowo Eda

Track position: 13

Release date: 2023

Genre:

CLICK HERE TO DOWNLOAD

Oruko Jesu by Tope Alabi Mp3 Music Lyrics

K′aiye to ta oruko Jesu, on dara fun wa
K’aiye to dale oruko Jesu, on dara fun wa
Eda yara pada sodo Jesu, ko dara fun o
K′aiye to ta oruko Jesu, on dara fun wa
K’aiye to dale oruko Jes, on dara fun wa
Eda yara pada sodo Jesu, ko le dara fun o
Eda yara pada sodo Jesu, ko le dara fun o

Omo gbo ohun Oluwa re ke tan tan si o oo, omo gbo
Omo gbo ohun Oluwa re ke tan tan si o oo, omo gbo
Ko ma si, eni to le gba o ninu iji aiye, ko ma si
Ko ma si, eni to le gba o ninu iji aiye, ko ma si

K’aiye to ta oruko Jesu, on dara fun wa
K′aiye to dale oruko Jesu, on dara fun wa
Eda yara pada sodo Jesu, ko dara fun o
K′aiye to ta oruko Jesu, on dara fun wa
K’aiye to dale oruko Jesu, on dara fun wa
Eda yara pada sodo Jesu, ko le dara fun o
Eda yara pada sodo Jesu, ko le dara fun o

Eni to gba wa la lowo iku oro, bee ni
O ja wa gba lowo egun ta bi wa si, bee ni
Owo to mo wa ko ni s′alai le gba wa, ra ra o
Eni to da eti koni s’alai gboron, bee ni

K′aiye to ta oruko Jesu, on dara fun wa
K’aiye to dale oruko Jesu, on dara fun wa
Eda yara pada sodo Jesu, ko le dara fun o
Eda yara pada sodo Jesu, ko le dara fun o

Aiye sare leje leje
Eniyan bu rin o f′ese ko ku
Awon ta mu latori aatan ta wa fi j’oba
Isoro de won sare eru won ti gba gbe eni to gba wa o
Ko ni s’alai gbawa tan won sare iku

Eda ro ju tan, on wa airoju o to ju su ni o, ee see
Eni to ni ala olumuse ala oruko re ni ala nla
Ese je je isoro de b′olorun soro mata Jesu, ofe la fun o
Odale pada ko ma ba bale lo
Oluta ofe igbala da owo won pada fun won
Ranti judasi ta ofe o pada pokun so
Eda yara pada sodo Oluwa re ko le dara fun o

K′aiye to ta oruko Jesu, on dara fun wa
K’aiye to dale oruko Jesu, on dara fun wa
Eda yara pada sodo Jesu, ko le dara fun o
Eda yara pada sodo Jesu, ko le dara fun o

What are your thoughts on the song? Post your comments below. Don’t forget to use the share buttons below to spread the word about this beautiful song.

Spread the love

Leave a Comment